042Kitchen

HOME | GOSPEL | AMERICAN | NIGERIAN | SOUTH AFRICAN | HIGHLIFE | REGGAESola Allyson – Mimo

Posted by: || Categories: Music

Mimo by Sola Allyson Mp3 Download

Get this gospel track from Sola Allyson which she titled Mimo. Sola Allyson is a Nigerian soul, folk, and gospel singer and songwriter. She came into limelight with the hit album Eji Owuro (2003)

Use the link below to stream and download Mimo by Sola Allyson.

Lyrics for Mimo by Sola Allyson

INTRO
Mimo ni ooo mimo ni ooo mimo
Mimo ni ooo mimo ni ooo mimo
Oluwa Olorun Eledumare to poo ni pa ati agbara

Mimo ni ooo mimo ni ooo mimo
Gbogbo iseda soo bee eemi na soo bee
Mimo ni ooo mimo ni ooo mimo

Lati oogun eemi mi
Mo juba re Ooba mimo
Awa ma ri di Oluwa
Mowo le fun Ooba toto
Leyin ree ko si ooo
Iwo to wa ni pekun kun imole
Iwo ni ekun ola ekun oogbon ekun agbara
Iwo nikan ni Ooba
Mo juba re Ooba mimo

Ooba to joko sori ite
Ooba to wa lori obiri aye ma se Oola re loo
Mowo le fun Ooba toto
Leyin ree ko si ooo
Aye ati Oorun nkoo ko si elomi
To ye ko gba ijuba wa bi o se Iwo
Iwo nikan ni Ooba
Mo wa ri fun ooo Oolola
Pelu iwa riri lati oogun emi mi
Imole to tan sinu okunkun mi

Download Music Here

 
 


0 Comments

LEAVE A COMMENT

Type Name Below

Type Comment Below

« | »